0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/plugins.md

5.5 KiB

id title
awọn ohun elo Awọn ohun elo

Verdaccio is a pluggable application. It can be extended in many ways, either new authentication methods, adding endpoints or using a custom storage.

There are 5 types of plugins:

Ti o ba nifẹ lati se agbedide asomọ ti ara rẹ, ka abala agbedide.

Ilo

Ifi sori ẹrọ

$> npm install --global verdaccio-activedirectory

verdaccio gẹgẹ bi ẹya ti o wa lati sinopia o ni ibasisẹpọ ẹlẹyin pẹlu awọn asomọ ti o ni ibasisẹpọ pẹlu sinopia@1.4.0. Ni iru eyi ifi sori ẹrọ na jẹ nkan kanna.

$> npm install --global sinopia-memory

Iṣeto

Sii faili config.yaml ki o si ṣe imudojuiwọn abala auth naa bi atẹle yi:

Iṣeto atilẹwa naa dabi iru eyi, nitoripe a lo ohun elo alakọmọ htpasswd ni atilẹwa pe ki o le yọ kuro nipa yiyọ awọn ila wọnyi.

Iṣeto Ifasẹsi

  htpasswd:
    file: ./htpasswd
    # max_users: 1000

ati rirọpo wọn pẹlu (toba sẹlẹ pe o pinnu lati lo ohun elo ldap.

auth:
  activedirectory:
    url: "ldap://10.0.100.1"
    baseDN: 'dc=sample,dc=local'
    domainSuffix: 'sample.local'

Awọn ohun elo Ifasẹsi ọlọpọlọpọ

This is technically possible, making the plugin order important, as the credentials will be resolved in order.

auth:
  htpasswd:
    file: ./htpasswd
    #max_users: 1000
  activedirectory:
    url: "ldap://10.0.100.1"
    baseDN: 'dc=sample,dc=local'
    domainSuffix: 'sample.local'

Iṣeto Middleware

Eyi jẹ apẹẹrẹ bi o ṣe le seto ohun asomọ middleware kan. Gbogbo awọn ohun asomọ gbọdọ wa ni asọye ninu aaye orukọ middlewares.

middlewares:
  audit:
    enabled: true

O le tẹle audit middle plugin bi apẹẹrẹ ipilẹ.

Iṣeto Ibi ipamọ

Eyi jẹ apẹẹrẹ bi o ṣe le ṣeto ohun asomọ ibi ipamọ kan. Gbogbo awọn ohun asomọ ibi ipamọ gbọdọ wa ni asọye ni aaye orukọ store.

store:
  memory:
    limit: 1000

Iṣeto Akori

Verdaccio n gbanilaaye lati rọpo Intafeesi olumulo pẹlu eyi to jẹ akanṣe, a n pe ni akori. Ni atilẹwa, o n lo @verdaccio/ui-theme ti o ba wa lati ilẹ, ṣugbọn, o le lo ohun ti o yatọ lati fi ohun asomọ ti ara rẹ sori ẹrọ.

<br />$> npm install --global verdaccio-theme-dark

Orukọ iṣaaju ohun asomọ naa gbọdọ bẹrẹ pẹlu verdaccio-theme, bibẹkọ ohun asomọ naa koni ṣiṣẹ.

You can load only one theme at a time and pass through options if you need it.

theme:
  dark:
    option1: foo
    option2: bar

Awọn ohun elo Ijogun

Awọn ohun elo Sinopia

Ti o ba ni igbarale lori eyikeyi ohun elo sinopia kankan, ranti pe adinku ti ba iwulo wọn atipe wọn le ma sisẹ mọ lọjọ iwaju.

Gbogbo awọn ohun elo sinopia gbọdọ ni ibaramu pẹlu gbogbo awọn ẹya ọjọ iwaju verdaccio. Amọ sa, a gba awọn olulọwọsi niyanju lati ṣi wọn nidi lọ si API igbalode ti verdaccio àti lílo ọrọ ibẹrẹ bii verdaccio-xx-name.