0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/plugins.md

135 lines
5.5 KiB
Markdown
Raw Normal View History

---
id: awọn ohun elo
title: "Awọn ohun elo"
---
Verdaccio is a pluggable application. It can be extended in many ways, either new authentication methods, adding endpoints or using a custom storage.
There are 5 types of plugins:
* [Ifasẹsi](plugin-auth.md)
* [Middleware](plugin-middleware.md)
* [Ibi ipamọ](plugin-storage.md)
* Custom Theme and filters
> Ti o ba nifẹ lati se agbedide asomọ ti ara rẹ, ka [abala](dev-plugins.md) agbedide.
## Ilo
### Ifi sori ẹrọ
```bash
$> npm install --global verdaccio-activedirectory
```
`verdaccio` gẹgẹ bi ẹya ti o wa lati sinopia o ni ibasisẹpọ ẹlẹyin pẹlu awọn asomọ ti o ni ibasisẹpọ pẹlu `sinopia@1.4.0`. Ni iru eyi ifi sori ẹrọ na jẹ nkan kanna.
$> npm install --global sinopia-memory
### Iṣeto
Sii faili `config.yaml` ki o si ṣe imudojuiwọn abala `auth` naa bi atẹle yi:
Iṣeto atilẹwa naa dabi iru eyi, nitoripe a lo ohun elo alakọmọ `htpasswd` ni atilẹwa pe ki o le yọ kuro nipa yiyọ awọn ila wọnyi.
### Iṣeto Ifasẹsi
```yaml
htpasswd:
file: ./htpasswd
# max_users: 1000
```
ati rirọpo wọn pẹlu (toba sẹlẹ pe o pinnu lati lo ohun elo `ldap`.
```yaml
auth:
activedirectory:
url: "ldap://10.0.100.1"
baseDN: 'dc=sample,dc=local'
domainSuffix: 'sample.local'
```
#### Awọn ohun elo Ifasẹsi ọlọpọlọpọ
This is technically possible, making the plugin order important, as the credentials will be resolved in order.
```yaml
auth:
htpasswd:
file: ./htpasswd
#max_users: 1000
activedirectory:
url: "ldap://10.0.100.1"
baseDN: 'dc=sample,dc=local'
domainSuffix: 'sample.local'
```
### Iṣeto Middleware
Eyi jẹ apẹẹrẹ bi o ṣe le seto ohun asomọ middleware kan. Gbogbo awọn ohun asomọ gbọdọ wa ni asọye ninu aaye orukọ **middlewares**.
```yaml
middlewares:
audit:
enabled: true
```
> O le tẹle [audit middle plugin](https://github.com/verdaccio/verdaccio-audit) bi apẹẹrẹ ipilẹ.
### Iṣeto Ibi ipamọ
Eyi jẹ apẹẹrẹ bi o ṣe le ṣeto ohun asomọ ibi ipamọ kan. Gbogbo awọn ohun asomọ ibi ipamọ gbọdọ wa ni asọye ni aaye orukọ **store**.
```yaml
store:
memory:
limit: 1000
```
### Iṣeto Akori
Verdaccio n gbanilaaye lati rọpo Intafeesi olumulo pẹlu eyi to jẹ akanṣe, a n pe ni **akori**. Ni atilẹwa, o n lo `@verdaccio/ui-theme` ti o ba wa lati ilẹ, ṣugbọn, o le lo ohun ti o yatọ lati fi ohun asomọ ti ara rẹ sori ẹrọ.
```bash
<br />$> npm install --global verdaccio-theme-dark
```
> Orukọ iṣaaju ohun asomọ naa gbọdọ bẹrẹ pẹlu `verdaccio-theme`, bibẹkọ ohun asomọ naa koni ṣiṣẹ.
You can load only one theme at a time and pass through options if you need it.
```yaml
theme:
dark:
option1: foo
option2: bar
```
## Awọn ohun elo Ijogun
### Awọn ohun elo Sinopia
> Ti o ba ni igbarale lori eyikeyi ohun elo sinopia kankan, ranti pe adinku ti ba iwulo wọn atipe wọn le ma sisẹ mọ lọjọ iwaju.
* [sinopia-npm](https://www.npmjs.com/package/sinopia-npm): ohun elo ifasẹsi fun sinopia to n ṣe atilẹyin ibi iforukọsilẹ npm kan.
* [sinopia-memory](https://www.npmjs.com/package/sinopia-memory): ohun elo ifasẹsi fun sinopia ti o n se itọju awọn olumulo sinu iranti.
* [sinopia-github-oauth-cli](https://www.npmjs.com/package/sinopia-github-oauth-cli)。.
* [sinopia-crowd](https://www.npmjs.com/package/sinopia-crowd): ohun elo ifasẹsi fun sinopia to n ṣe atilẹyin atlassian crowd.
* [sinopia-activedirectory](https://www.npmjs.com/package/sinopia-activedirectory): Ohun elo ifasẹsi Active Directory fun sinopia.
* [sinopia-github-oauth](https://www.npmjs.com/package/sinopia-github-oauth): ohun elo ifasẹsi fun sinopia2, to n ṣe atilẹyin github oauth web flow.
* [sinopia-delegated-auth](https://www.npmjs.com/package/sinopia-delegated-auth): Ohun elo ifasẹsi Sinopia ti o n ṣe atunpin ifasẹsi si HTTP URL miran
* [sinopia-altldap](https://www.npmjs.com/package/sinopia-altldap): Ohun elo ifasẹsi LDAP Miiran fun Sinopia
* [sinopia-request](https://www.npmjs.com/package/sinopia-request): Ohun elo-ifasẹsi to rọrun ati to kun pẹlu iṣeto lati lo API ita kan.
* [sinopia-htaccess-gpg-email](https://www.npmjs.com/package/sinopia-htaccess-gpg-email): Pilẹṣẹ ọrọ igbaniwọle ni ilana htaccess, pa ni aroko pẹlu GPG ki o si firanṣẹ nipasẹ MailGun API si awọn olumulo.
* [sinopia-mongodb](https://www.npmjs.com/package/sinopia-mongodb): Ohun elo-ifasẹsi to rọrun ati to kun pẹlu iṣeto lati lo ibi ipamọ data mongodb.
* [sinopia-htpasswd](https://www.npmjs.com/package/sinopia-htpasswd): ohun elo ifasẹsi fun sinopia to n ṣe atilẹyin ilana htpasswd.
* [sinopia-leveldb](https://www.npmjs.com/package/sinopia-leveldb): ohun elo ifasẹsi to ni atilẹyin leveldb fun sinopia private npm.
* [sinopia-gitlabheres](https://www.npmjs.com/package/sinopia-gitlabheres): Ohun elo ifasẹsi Gitlab fun sinopia.
* [sinopia-gitlab](https://www.npmjs.com/package/sinopia-gitlab): Ohun elo ifasẹsi Gitlab fun sinopia
* [sinopia-ldap](https://www.npmjs.com/package/sinopia-ldap): Ohun elo ifasẹsi LDAP fun sinopia.
* [sinopia-github-oauth-env](https://www.npmjs.com/package/sinopia-github-oauth-env) Ohun elo ifasẹsi Sinopia pẹlu github oauth web flow.
> Gbogbo awọn ohun elo sinopia gbọdọ ni ibaramu pẹlu gbogbo awọn ẹya ọjọ iwaju verdaccio. Amọ sa, a gba awọn olulọwọsi niyanju lati ṣi wọn nidi lọ si API igbalode ti verdaccio àti lílo ọrọ ibẹrẹ bii *verdaccio-xx-name*.