0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/dev-plugins.md

1.9 KiB

id title
dev-plugins Ṣiṣe agbedide Awọn ohun elo

Awọn ọna pupọ lo wa lati fa verdaccio gun si, iru awọn ohun elo ti atilẹyin wa fun ni:

We recommend developing plugins using our Typescript type definitions.

Other plugins

The following plugins are valid and in process of incubation.

Ohun elo Akori

The plugin must return a function that returns a string. The string should be the absolute location of the root of your user interface.

API

const path = require('path');

module.exports = (...arguments) => {
  return path.join(__dirname, 'static');
};

O jẹ pataki pe orukọ ohun elo naa gbọdọ bẹrẹ pẹlu afikun iṣaaju verdaccio-theme-.

Apẹẹrẹ Akori

Ohun elo Asẹ

Lati 4.1.0

Awọn ohun elo asẹ jẹ ṣiṣe nitori ibeere fun lati le ni anfani lati ya metadata sọtọ kuro ni ara awọn uplink.

Alaye siwaju si wa ninu PR.

filters:
   storage-filter-blackwhitelist:
     filter_file: /path/to/file

API

Ọna filter_metadata naa yoo gba ọ laaye lati ya metadata ti o wa lati eyikeyi uplink sọtọ, o jẹ eyi to da lori Ileri ati pe o ni lati tun da metadata kanna pada pẹlu atunṣe.

Do not remove properties from the metadata, try to do not mutate rather return a new object.

interface IPluginStorageFilter<T> extends IPlugin<T> {
    filter_metadata(packageInfo: Package): Promise<Package>;
}