3.2 KiB
id | title |
---|---|
authentication | Ifasẹsi |
The authentication is tied to the auth plugin you are using. The package restrictions are also handled by the Package Access.
The client authentication is handled by the npm
client itself. Once you log in to the application:
npm adduser --registry http://localhost:4873
Aami kan ma jẹ ṣisẹda ninu npm
faili iṣeto ti igbalejo rẹ wa ninu foda ile olumulo rẹ. Fun ẹkunrẹrẹ alaye nipa .npmrc
ka iwe alasẹ.
cat .npmrc
registry=http://localhost:5555/
//localhost:5555/:_authToken="secretVerdaccioToken"
//registry.npmjs.org/:_authToken=secretNpmjsToken
Igbejade alainidamọ
verdaccio
allows you to enable anonymous publish. To achieve that you will need to correctly set up your packages access.
Fun apẹẹrẹ:
'my-company-*':
access: $anonymous
publish: $anonymous
proxy: npmjs
Bi apejuwe rẹ ti ṣe jẹ ṣiṣe lori ọrọ #212 titi npm@5.3.0
atipe gbogbo awọn ifilọlẹ kekere koni fayegba ọ lati se atẹjade laisi aami kankan.
Nini oye Awọn ẹgbẹ akojọpọ
Itunmọ $all
ati $anonymous
As you know Verdaccio uses htpasswd
by default. Ohun elo yẹn ko ṣe amuṣiṣẹ awọn ọna naa allow_access
, allow_publish
and allow_unpublish
. Nitorina, Verdaccio ma mojuto iyẹn ni ọna wọnyi:
- Ti o ko ba wọle (o jẹ alainidamọ),
$all
ati$anonymous
tumọ si nkankan na. - If you are logged in,
$anonymous
won't be part of your groups and$all
will match any logged user. A new group$authenticated
will be added to your group list.
Please note: $all
will match all users, whether logged in or not.
Ohun elo ifasẹsi atilẹwa nikan ni iwa iṣaaju yẹn bawi. Ti o ba n lo ohun elo akanṣe ati ti iru ohun elo bẹ ba n se imuṣiṣẹ allow_access
, allow_publish
tabi allow_unpublish
, awọn ipinnu ti iwọle naa da lori ohun elo naa funrararẹ. Verdaccio ma ṣeto awọn ẹgbẹ akojọpọ atilẹwa nikan.
Jẹ ki a ṣe atungbeyẹwo ni ṣoki:
- logged in:
$all
and$authenticated
+ groups added by the plugin. - logged out (anonymous):
$all
and$anonymous
.
htpasswd atilẹwa
In order to simplify the setup, verdaccio
uses a plugin based on htpasswd
. Since version v3.0.x the verdaccio-htpasswd
plugin is used by default.
auth:
htpasswd:
file: ./htpasswd
# Maximum amount of users allowed to register, defaults to "+inf".
# You can set this to -1 to disable registration.
#max_users: 1000
Ohun ini | Iru | Ti o nilo | Apẹẹrẹ | Atilẹyin | Apejuwe |
---|---|---|---|---|---|
faili | okun | Bẹẹni | ./htpasswd | gbogbo | faili to gbalejo awọn iwe ẹri alaroko |
max_users | nọmba | Rara | 1000 | gbogbo | ṣeto gbedeke iye awọn olumulo |
In case you decide to prevent users from signing up themselves, you can set max_users: -1
.