--- id: authentication title: "Ifasẹsi" --- The authentication is tied to the auth [plugin](plugins.md) you are using. The package restrictions are also handled by the [Package Access](packages.md). The client authentication is handled by the `npm` client itself. Once you log in to the application: ```bash npm adduser --registry http://localhost:4873 ``` Aami kan ma jẹ ṣisẹda ninu `npm` faili iṣeto ti igbalejo rẹ wa ninu foda ile olumulo rẹ. Fun ẹkunrẹrẹ alaye nipa `.npmrc` ka [ iwe alasẹ](https://docs.npmjs.com/files/npmrc). ```bash cat .npmrc registry=http://localhost:5555/ //localhost:5555/:_authToken="secretVerdaccioToken" //registry.npmjs.org/:_authToken=secretNpmjsToken ``` #### Igbejade alainidamọ `verdaccio` allows you to enable anonymous publish. To achieve that you will need to correctly set up your [packages access](packages.md). Fun apẹẹrẹ: ```yaml 'my-company-*': access: $anonymous publish: $anonymous proxy: npmjs ``` Bi apejuwe rẹ ti ṣe jẹ ṣiṣe [lori ọrọ #212](https://github.com/verdaccio/verdaccio/issues/212#issuecomment-308578500) titi `npm@5.3.0` atipe gbogbo awọn ifilọlẹ kekere **koni fayegba ọ lati se atẹjade laisi aami kankan**. ## Nini oye Awọn ẹgbẹ akojọpọ ### Itunmọ `$all` ati `$anonymous` As you know *Verdaccio* uses `htpasswd` by default. Ohun elo yẹn ko ṣe amuṣiṣẹ awọn ọna naa `allow_access`, `allow_publish` and `allow_unpublish`. Nitorina, *Verdaccio* ma mojuto iyẹn ni ọna wọnyi: * Ti o ko ba wọle (o jẹ alainidamọ), `$all` ati `$anonymous` tumọ si nkankan na. * If you are logged in, `$anonymous` won't be part of your groups and `$all` will match any logged user. A new group `$authenticated` will be added to your group list. Please note: `$all` **will match all users, whether logged in or not**. **Ohun elo ifasẹsi atilẹwa nikan ni iwa iṣaaju yẹn bawi**. Ti o ba n lo ohun elo akanṣe ati ti iru ohun elo bẹ ba n se imuṣiṣẹ `allow_access`, `allow_publish` tabi `allow_unpublish`, awọn ipinnu ti iwọle naa da lori ohun elo naa funrararẹ. Verdaccio ma ṣeto awọn ẹgbẹ akojọpọ atilẹwa nikan. Jẹ ki a ṣe atungbeyẹwo ni ṣoki: * **logged in**: `$all` and `$authenticated` + groups added by the plugin. * **logged out (anonymous)**: `$all` and `$anonymous`. ## htpasswd atilẹwa In order to simplify the setup, `verdaccio` uses a plugin based on `htpasswd`. Since version v3.0.x the `verdaccio-htpasswd` plugin is used by default. ```yaml auth: htpasswd: file: ./htpasswd # Maximum amount of users allowed to register, defaults to "+inf". # You can set this to -1 to disable registration. #max_users: 1000 ``` | Ohun ini | Iru | Ti o nilo | Apẹẹrẹ | Atilẹyin | Apejuwe | | --------- | ----- | --------- | ---------- | -------- | ------------------------------------- | | faili | okun | Bẹẹni | ./htpasswd | gbogbo | faili to gbalejo awọn iwe ẹri alaroko | | max_users | nọmba | Rara | 1000 | gbogbo | ṣeto gbedeke iye awọn olumulo | In case you decide to prevent users from signing up themselves, you can set `max_users: -1`.