0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-10 23:39:31 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/ci.md

948 B

id title
ci Imuṣiṣẹpọ Alainidaduro

Verdaccio le ṣe lo pẹlu awọn pilatifọọmu imuṣiṣẹpọ alainidaduro (CI) lati fi sori ẹrọ tabi ṣe agbejade awọn akopọ. Nigbati NPM ba n jẹ lilo lati fi se agbekalẹ akopọ ikọkọ kan ni ayika CI fun igba akọkọ, o le ṣe alabapade awọn iṣoro kan. Aṣẹ npm login jẹ didalara lati ṣe lo ni ọna ifọrọjomitoro ọrọ. Eleyi n sagbedide ọrọ kan ni CI, awọn iwe afọwọkọ, abbl. Ni isalẹ ni awọn arokọ diẹ ti o n sọ ni asọye bi o ṣe le lo npm login lori oriṣiriṣi awọn pilatifọọmu CI.