--- id: ci title: "Imuṣiṣẹpọ Alainidaduro" --- Verdaccio le ṣe lo pẹlu awọn pilatifọọmu imuṣiṣẹpọ alainidaduro (CI) lati fi sori ẹrọ tabi ṣe agbejade awọn akopọ. Nigbati NPM ba n jẹ lilo lati fi se agbekalẹ akopọ ikọkọ kan ni ayika CI fun igba akọkọ, o le ṣe alabapade awọn iṣoro kan. Aṣẹ `npm login` jẹ didalara lati ṣe lo ni ọna ifọrọjomitoro ọrọ. Eleyi n sagbedide ọrọ kan ni CI, awọn iwe afọwọkọ, abbl. Ni isalẹ ni awọn arokọ diẹ ti o n sọ ni asọye bi o ṣe le lo `npm login` lori oriṣiriṣi awọn pilatifọọmu CI. - [Travis CI](https://remysharp.com/2015/10/26/using-travis-with-private-npm-deps) - [Circle CI 1.0](https://circleci.com/docs/1.0/npm-login/) tabi [Circle CI 2.0](https://circleci.com/docs/2.0/deployment-integrations/#npm) - [Gitlab CI](https://www.exclamationlabs.com/blog/continuous-deployment-to-npm-using-gitlab-ci/)