0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/uplinks.md

87 lines
No EOL
5.9 KiB
Markdown

---
id: uplinks
title: "Uplinks"
---
*uplink* jẹ ọna asopọ pẹlu ibi iforukọsilẹ ti ita ti o n pese iwọle si awọn akojọ ti ita.
![Uplinks](https://user-images.githubusercontent.com/558752/52976233-fb0e3980-33c8-11e9-8eea-5415e6018144.png)
### Ilo
```yaml
uplinks:
npmjs:
url: https://registry.npmjs.org/
server2:
url: http://mirror.local.net/
timeout: 100ms
server3:
url: http://mirror2.local.net:9000/
baduplink:
url: http://localhost:55666/
```
### Iṣeto
O le ṣe asọye awọn uplink ọlọpọlọpọ atipe ọkọọkan wọn gbọdọ ni orukọ to dayatọ (kọkọrọ). Wọn le ni awọn ohun wọnyi:
| Ohun ini | Iru | Ti o nilo | Apẹẹrẹ | Atilẹyin | Apejuwe | Atilẹwa |
| --------------- | ------- | --------- | --------------------------------------- | -------- | ------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------------ | ---------------- |
| url | okun | Bẹẹni | https://registry.npmjs.org/ | gbogbo | url ibi iforukọsilẹ naa | npmjs |
| ca | okun | Rara | ~./ssl/client.crt' | gbogbo | iwe ẹri ipa ọna SSL | Kosi atilẹda |
| akoko idawọduro | okun | Rara | 100ms | gbogbo | ṣeto akoko idawọduro tuntun fun ìbéèrè naa | 30s |
| maxage | okun | Rara | 10m | gbogbo | akoko aala si apo iranti naa fẹsẹmulẹ | 2m |
| fail_timeout | okun | Rara | 10m | gbogbo | n ṣe asọye akoko gigaju nigba ti ìbéèrè ma di ikuna | 5m |
| max_fails | nọmba | Rara | 2 | gbogbo | se adinku iye ibeere ikuna to pọju | 2 |
| apo iranti | boolean | Rara | [otitọ, irọ] | >= 2.1 | ko gbogbo awọn tarball ọna jijin si ipamọ apo iranti | otitọ |
| auth | akojọ | Rara | [wo isalẹ](uplinks.md#auth-property) | >= 2.5 | n yan akọle 'Authorization' naa [alaye siwaju sii](http://blog.npmjs.org/post/118393368555/deploying-with-npm-private-modules) | o ti jẹ yiyọkuro |
| awọn akọle | akojọ | Rara | authorization: "Bearer SecretJWToken==" | gbogbo | akojọ awọn akọle akanṣe fun uplink naa | o ti jẹ yiyọkuro |
| strict_ssl | boolean | Rara | [otitọ, irọ] | >= 3.0 | To ba jẹ otitọ, o nilo ki awọn iwe ẹri SSL fẹsẹmulẹ. | otitọ |
| agent_options | object | Rara | maxSockets: 10 | >= 4.0.2 | options for the HTTP or HTTPS Agent responsible for managing uplink connection persistence and reuse [more info](https://nodejs.org/api/http.html#http_class_http_agent) | Kosi atilẹda |
#### Ohun ini Auth
Ohun ini `auth` fun ọ laaye lati lo aami auth kan pẹlu uplink. Lilo iyipada ayika atilẹwa naa:
```yaml
uplinks:
private:
url: https://private-registry.domain.com/registry
auth:
type: bearer
token_env: true # defaults to `process.env['NPM_TOKEN']`
```
tabi nipasẹ iyipada ayika to jẹ yiyan:
```yaml
uplinks:
private:
url: https://private-registry.domain.com/registry
auth:
type: bearer
token_env: FOO_TOKEN
```
`token_env: FOO_TOKEN`labẹnu ma lo `process.env['FOO_TOKEN']`
tabi nipa yiyan aami kan taarata:
```yaml
uplinks:
private:
url: https://private-registry.domain.com/registry
auth:
type: bearer
token: "token"
```
> Akiyesi: `token` ṣe pataki ju `token_env` lọ
### O Gbọdọ Mọ
* Uplinks gbọdọ ni ibamu pẹlu awọn ibi iforukọsilẹ pẹlu `npm` awọn aaye opin. Fun apẹẹrẹ: *verdaccio*, `sinopia@1.4.0`, *npmjs registry*, *yarn registry*, *JFrog*, *Nexus* ati siwaju sii.
* Ṣiṣeto `cache` si eke yoo ṣe iranlọwọ lati pa aaye mọ ninu ààyè ìtọ́jú alafojuri rẹ. Eyi yoo yago fun itọju `tarballs` sugbọn [o ma fi metadata pamọ sinu awọn foda](https://github.com/verdaccio/verdaccio/issues/391).
* Titayọ pẹlu ọpọlọpọ uplinks le mu ifasẹyin ba isawari awọn akopọ rẹ ti o ti yẹ fun ibeere kọọkan ti onibara npm kan ṣe, verdaccio n ṣe ipe 1 fun uplink kọọkan.
* Ilana (timeout, maxage and fail_timeout) tẹle [awọn odiwọn iwọn NGINX](http://nginx.org/en/docs/syntax.html)