0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/cli.md

2.1 KiB

id title
cli Irinṣẹ Ila aṣẹ

The Verdaccio CLI is your tool to start and stop the application.

Awọn aṣẹ

verdaccio --listen 4000 --config ~./config.yaml
Aṣẹ Atilẹwa Apẹẹrẹ Apejuwe
--listen \ -l 4873 -p 7000 ibudo http
--config \ -c ~/.local/verdaccio/config.yaml ~./config.yaml faili iṣeto naa
--info \ -i n ṣe atẹjade alaye ayika ibilẹ

Aaye faili iṣeto atilẹwa

To locate the home directory, we rely on $XDG_DATA_HOME as a first choice and for Windows environments we look for the APPDATA environment variable.

Ọna faili iṣeto

Config files should be YAML, JSON or a NodeJS module. YAML format is detected by parsing config file extension (yaml or yml, case insensitive).

Aaye ibi ipamọ atilẹwa

We use the $XDG_DATA_HOME environment by variable default to locate the storage by default which should be the same as $HOME/.local/share. Ti o ba n lo ibi ipamọ akanṣe kan, aaye yii ko ṣe pataki.

Aaye faili ibi ipamọ data atilẹwa

Aaye faili ibi ipamọ data atilẹwa wa ninu aaye ibi ipamọ. Bibẹrẹ pẹlu ẹya 4.0.0, orukọ faili ibi ipamọ data yoo jẹ .verdaccio-db.json fun ifisori ẹrọ tuntun ti Verdaccio. Nigbati isagbega olupese Verdaccio kan to ti wa tẹlẹ ba n waye, orukọ faili naa yoo si ma jẹ .sinopia-db.json.

Environment variables

Full list of environment variables.

  • VERDACCIO_HANDLE_KILL_SIGNALS to enable gracefully shutdown (since v4.12.0)