0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/e2e.md

3.2 KiB
Raw Blame History

id title
e2e Idanwo Opin si Opin

Awọn iṣẹ akanṣe kan ma n ṣeto awọn akojọ ni awọn ibi ipamọ ti ọlọpọlọpọ-akojọ tabi onibi ipamọ kan. Idanwo E2E jẹ akọle ti o ma n saba yẹ fun Awọn Intafeesi Olumulo nikan, ṣugbọn lati oju iwoye ti Node.js, sise atẹjade awọn akojọ naa tun nilo lati ni idanwo.

Ọna abayọ: ibi iforukọsilẹ npm ibilẹ kan. https://t.co/kvcyVANVSK

— Dan Abramov (@dan_abramov) osu kini ọjọ kọkanla ọdun 2018

Iru ọna yẹn ti jẹ eyi to soro gidi gan lati ni aṣeyọri pẹlu riro iwọnyi:

  • Iselọpọ awọn akojọ canary lori awọn iṣẹ gbogbogbo ni o dabi pe o ko kin se imọran to dara
  • Awọn ibi iforukọsilẹ OSS agbalejo-alara ẹni kan ti wuwo ju
  • Awọn awujọ alaisilorila (awọn nẹtiwọki aladani)

Verdaccio jẹ ibi iforukọsilẹ fifuyẹ pẹlu iṣeto-odo ti o ni ibamu didanmọran pẹlu eyikeyi E2E + CI ilana iṣẹ.

Imuṣiṣẹ

Ko ti si ọta fadaka kankan, imuṣiṣẹ kọọkan dabi pe o jẹ pato fun iṣẹ akanṣe kọọkan, o le ṣayẹwo diẹ ninu wọn ni okun atẹle yii tẹ ibi.

Apẹẹrẹ nipa lilo Bash

Eyi ni apẹẹrẹ to rọrun julọ nipa lilo Verdaccio ninu iwe afọwọkọ bash kan (ti o jẹ fifajade lati create-react-app).

#!/bin/sh

set -e

local_registry="http://0.0.0.0:4873"

# start local registry
tmp_registry_log=`mktemp`
sh -c "mkdir -p $HOME/.config/verdaccio"
sh -c "cp --verbose /config.yaml $HOME/.config/verdaccio/config.yaml"
sh -c "nohup verdaccio --config $HOME/.config/verdaccio/config.yaml &>$tmp_registry_log &"
# wait for `verdaccio` to boot
grep -q 'http address' <(tail -f $tmp_registry_log)
# login so we can publish packages
sh -c "npm-auth-to-token -u test -p test -e test@test.com -r $local_registry"
# Run nmp command
sh -c "npm --registry $local_registry publish"

Who is using it for E2E?