mirror of
https://github.com/verdaccio/verdaccio.git
synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
10 lines
No EOL
948 B
Markdown
10 lines
No EOL
948 B
Markdown
---
|
|
id: ci
|
|
title: "Imuṣiṣẹpọ Alainidaduro"
|
|
---
|
|
|
|
Verdaccio le ṣe lo pẹlu awọn pilatifọọmu imuṣiṣẹpọ alainidaduro (CI) lati fi sori ẹrọ tabi ṣe agbejade awọn akopọ. Nigbati NPM ba n jẹ lilo lati fi se agbekalẹ akopọ ikọkọ kan ni ayika CI fun igba akọkọ, o le ṣe alabapade awọn iṣoro kan. Aṣẹ `npm login` jẹ didalara lati ṣe lo ni ọna ifọrọjomitoro ọrọ. Eleyi n sagbedide ọrọ kan ni CI, awọn iwe afọwọkọ, abbl. Ni isalẹ ni awọn arokọ diẹ ti o n sọ ni asọye bi o ṣe le lo `npm login` lori oriṣiriṣi awọn pilatifọọmu CI.
|
|
|
|
- [Travis CI](https://remysharp.com/2015/10/26/using-travis-with-private-npm-deps)
|
|
- [Circle CI 1.0](https://circleci.com/docs/1.0/npm-login/) tabi [Circle CI 2.0](https://circleci.com/docs/2.0/deployment-integrations/#npm)
|
|
- [Gitlab CI](https://www.exclamationlabs.com/blog/continuous-deployment-to-npm-using-gitlab-ci/) |