0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-10 23:39:31 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/uplinks.md

5.9 KiB

id title
uplinks Uplinks

uplink jẹ ọna asopọ pẹlu ibi iforukọsilẹ ti ita ti o n pese iwọle si awọn akojọ ti ita.

Uplinks

Ilo

uplinks:
  npmjs:
   url: https://registry.npmjs.org/
  server2:
    url: http://mirror.local.net/
    timeout: 100ms
  server3:
    url: http://mirror2.local.net:9000/
  baduplink:
    url: http://localhost:55666/

Iṣeto

O le ṣe asọye awọn uplink ọlọpọlọpọ atipe ọkọọkan wọn gbọdọ ni orukọ to dayatọ (kọkọrọ). Wọn le ni awọn ohun wọnyi:

Ohun ini Iru Ti o nilo Apẹẹrẹ Atilẹyin Apejuwe Atilẹwa
url okun Bẹẹni https://registry.npmjs.org/ gbogbo url ibi iforukọsilẹ naa npmjs
ca okun Rara ~./ssl/client.crt' gbogbo iwe ẹri ipa ọna SSL Kosi atilẹda
akoko idawọduro okun Rara 100ms gbogbo ṣeto akoko idawọduro tuntun fun ìbéèrè naa 30s
maxage okun Rara 10m gbogbo akoko aala si apo iranti naa fẹsẹmulẹ 2m
fail_timeout okun Rara 10m gbogbo n ṣe asọye akoko gigaju nigba ti ìbéèrè ma di ikuna 5m
max_fails nọmba Rara 2 gbogbo se adinku iye ibeere ikuna to pọju 2
apo iranti boolean Rara [otitọ, irọ] >= 2.1 ko gbogbo awọn tarball ọna jijin si ipamọ apo iranti otitọ
auth akojọ Rara wo isalẹ >= 2.5 n yan akọle 'Authorization' naa alaye siwaju sii o ti jẹ yiyọkuro
awọn akọle akojọ Rara authorization: "Bearer SecretJWToken==" gbogbo akojọ awọn akọle akanṣe fun uplink naa o ti jẹ yiyọkuro
strict_ssl boolean Rara [otitọ, irọ] >= 3.0 To ba jẹ otitọ, o nilo ki awọn iwe ẹri SSL fẹsẹmulẹ. otitọ
agent_options object Rara maxSockets: 10 >= 4.0.2 options for the HTTP or HTTPS Agent responsible for managing uplink connection persistence and reuse more info Kosi atilẹda

Ohun ini Auth

Ohun ini auth fun ọ laaye lati lo aami auth kan pẹlu uplink. Lilo iyipada ayika atilẹwa naa:

uplinks:
  private:
    url: https://private-registry.domain.com/registry
    auth:
      type: bearer
      token_env: true # defaults to `process.env['NPM_TOKEN']`

tabi nipasẹ iyipada ayika to jẹ yiyan:

uplinks:
  private:
    url: https://private-registry.domain.com/registry
    auth:
      type: bearer
      token_env: FOO_TOKEN

token_env: FOO_TOKENlabẹnu ma lo process.env['FOO_TOKEN']

tabi nipa yiyan aami kan taarata:

uplinks:
  private:
    url: https://private-registry.domain.com/registry
    auth:
      type: bearer
      token: "token"

Akiyesi: token ṣe pataki ju token_env lọ

O Gbọdọ Mọ

  • Uplinks gbọdọ ni ibamu pẹlu awọn ibi iforukọsilẹ pẹlu npm awọn aaye opin. Fun apẹẹrẹ: verdaccio, sinopia@1.4.0, npmjs registry, yarn registry, JFrog, Nexus ati siwaju sii.
  • Ṣiṣeto cache si eke yoo ṣe iranlọwọ lati pa aaye mọ ninu ààyè ìtọ́jú alafojuri rẹ. Eyi yoo yago fun itọju tarballs sugbọn o ma fi metadata pamọ sinu awọn foda.
  • Titayọ pẹlu ọpọlọpọ uplinks le mu ifasẹyin ba isawari awọn akopọ rẹ ti o ti yẹ fun ibeere kọọkan ti onibara npm kan ṣe, verdaccio n ṣe ipe 1 fun uplink kọọkan.
  • Ilana (timeout, maxage and fail_timeout) tẹle awọn odiwọn iwọn NGINX