2.3 KiB
id | title |
---|---|
ssl | Ṣeto Awọn iwe ẹri SSL |
Follow these instructions to configure an SSL certificate to serve an npm registry over HTTPS.
-
Ṣe imudojuiwọn ohun elo itẹtisi ni
~/.config/verdaccio/config.yaml
rẹ:listen: 'https://your.domain.com/'
Lọgan ti o ti se imudojuiwọn ohun elo itẹtisi ati gbigbiyanju lati ṣe imuṣiṣẹ verdaccio lẹẹkansi, yoo beere fun awọn iwe ẹri.
-
Pilẹṣẹ awọn iwe ẹri rẹ
$ openssl genrsa -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem 2048 $ openssl req -new -sha256 -key /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem $ openssl x509 -req -in /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem -signkey /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-cert.pem
* Ṣatunkọ faili iṣeto rẹ `/Users/user/.config/verdaccio/config.yaml` ki o si se afikun abala wọnyi:
https: key: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem cert: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-cert.pem ca: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem
<br />Ni ọna miiran, ti o ba ni iwe ẹri pẹlu ilana ti `server.pfx`, o le se afikun awọn abala iṣeto wọnyii: (Gbolohun irekọja naa kii se dandan ati pe o ma jẹ ni nilo nikan to ba jẹ pe iwe ẹri rẹ jẹ alaroko.)
https: pfx: /Users/user/.config/verdaccio/server.pfx passphrase: 'secret' ````
O le ri alaye diẹ sii lori awọn ariyanjiyan key
, cert
, ca
, pfx
, ati passphrase
ni Iwe akọsilẹ Oju ipade
-
Se imusisẹ
verdaccio
ninu ila aṣẹ rẹ. -
Ṣii ẹrọ aṣàwákiri ayelujara ki o si ṣabẹwo si
https://your.domain.com:port/
Awọn itọsọna wọnyi ma n saba fẹsẹmulẹ labẹ OSX ati Linux; lori Windows awọn ọna naa yoo yatọ, ṣugbọn awọn igbesẹ naa jẹ bakanna.
Docker
Ti o ba n lo aworan Docker, o ni lati ṣeto iyipada ayika VERDACCIO_PROTOCOL
si https
, gẹgẹ bi ariyanjiyan listen
se jẹ pipese ninu Dockerfile naa ati pe o foju fo ti inu faili iṣeto rẹ.
O tun le ṣeto iyipada ayika VERDACCIO_PORT
ti o ba nlo ibudo miiran to yatọ si 4873
.