0
Fork 0
mirror of https://github.com/verdaccio/verdaccio.git synced 2025-02-17 23:45:29 -05:00
verdaccio/website/translated_docs/yo-NG/ssl.md

46 lines
2.3 KiB
Markdown
Raw Normal View History

---
id: ssl
title: "Ṣeto Awọn iwe ẹri SSL"
---
Follow these instructions to configure an SSL certificate to serve an npm registry over HTTPS.
* Ṣe imudojuiwọn ohun elo itẹtisi ni `~/.config/verdaccio/config.yaml` rẹ:
listen: 'https://your.domain.com/'
Lọgan ti o ti se imudojuiwọn ohun elo itẹtisi ati gbigbiyanju lati ṣe imuṣiṣẹ verdaccio lẹẹkansi, yoo beere fun awọn iwe ẹri.
* Pilẹṣẹ awọn iwe ẹri rẹ
$ openssl genrsa -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem 2048
$ openssl req -new -sha256 -key /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem
$ openssl x509 -req -in /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem -signkey /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-cert.pem
````
* Ṣatunkọ faili iṣeto rẹ `/Users/user/.config/verdaccio/config.yaml` ki o si se afikun abala wọnyi:
https: key: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem cert: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-cert.pem ca: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem
<br />Ni ọna miiran, ti o ba ni iwe ẹri pẹlu ilana ti `server.pfx`, o le se afikun awọn abala iṣeto wọnyii: (Gbolohun irekọja naa kii se dandan ati pe o ma jẹ ni nilo nikan to ba jẹ pe iwe ẹri rẹ jẹ alaroko.)
https: pfx: /Users/user/.config/verdaccio/server.pfx passphrase: 'secret' ````
O le ri alaye diẹ sii lori awọn ariyanjiyan `key`, `cert`, `ca`, `pfx`, ati `passphrase` ni [Iwe akọsilẹ Oju ipade](https://nodejs.org/api/tls.html#tls_tls_createsecurecontext_options)
* Se imusisẹ `verdaccio` ninu ila aṣẹ rẹ.
* Ṣii ẹrọ aṣàwákiri ayelujara ki o si ṣabẹwo si `https://your.domain.com:port/`
Awọn itọsọna wọnyi ma n saba fẹsẹmulẹ labẹ OSX ati Linux; lori Windows awọn ọna naa yoo yatọ, ṣugbọn awọn igbesẹ naa jẹ bakanna.
## Docker
Ti o ba n lo aworan Docker, o ni lati ṣeto iyipada ayika `VERDACCIO_PROTOCOL` si `https`, gẹgẹ bi ariyanjiyan `listen` se jẹ pipese ninu [Dockerfile](https://github.com/verdaccio/verdaccio/blob/master/Dockerfile#L43) naa ati pe o foju fo ti inu faili iṣeto rẹ.
O tun le ṣeto iyipada ayika `VERDACCIO_PORT` ti o ba nlo ibudo miiran to yatọ si `4873`.